Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Olumuyiwa' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Gospel Hits Internacionais

Varios-artistas

Hoy Es Viernes

Varios-artistas

Clasicos de la salsa

Varios-artistas

Baladas En Espanol De Los 60s 70s 80s

Artist profile picture

Olumuyiwa

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

Jọwọ, bá mi gb'ẹ'ni mi d'ókè odò
Ó parí iṣẹ' rẹ o, ó ń dàbọ' re 'lé
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánitọ'mọ ńré lé rẹ' o
Ọlọ'kọ', jọwọ, bá mi ṣ'ẹni mi ní jẹ'jẹ'
Ó j'èrè l'ọ'jà ó sì tún fì'wà lò'gbà
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ Oní-ìhìnrere
Abánikẹ'mọ ńré lé o

Jọwọ, bá mi gb'ẹ'ni mi d'ókè odò
Ó bo'rí ìdánwò, ó yè kooro láyé
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ Oní-ìhìnrere
Abánitọ'mọ ńré lé rẹ' o
Ọlọkọ, jọ'wọ', bá mi ṣ'ẹni mi ní jẹ'jẹ
Ó ṣe'wọn t'ó lè ṣe o, ó là'nà ayọ' ka'lẹ'
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánikẹ'mọ ńré lé rẹ' o

B'ó m'órin s'ẹ'nu, b'ó ṣe t'àdúrà
Gbogbo ilé á mì tìtì-tìtì
B'ó bá ṣe ká fi'jó ṣè 'dúpẹ'
Ẹ'yin ẹ ṣá ma wò ó

Jọwọ, bá mi gb'ẹ'ni mi d'ókè odò
Ó parí iṣẹ' rẹ, ó ń dàbọ' re 'lé
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánitọ'mọ ńré lé rẹ o
Ọlọkọ, jọwọ, bá mi ṣ'ẹni mi ní jẹ'jẹ'
Ó j'èrè l'ọ'jà, ó sì tún fì'wà lò'gbà
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánikẹ'mọ ńré lé o

Jọwọ, bá mi gb'ẹ'ni mi d'ókè odò
Ó parí iṣẹ' rẹ', ó ndàbọ' re 'lé
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánitọ'mọ ńré lé rẹ' o
Ọlọkọ, jọwọ, bá mi ṣ'ẹni mi ní jẹ'jẹ'
Ó j'èrè l'ọ'jà, ó sì tún fì'wà lò'gbà
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánikẹ'mọ ńré lé o

B'ó m'órin s'ẹ'nu, b'ó ṣe t'àdúrà
Gbogbo ilé á mì tìtì-tìtì
B'ó bá ṣe ká fi'jó ṣè 'dúpẹ'
Ẹ'yin ẹ ṣá ma wò ó

Jọwọ, bá mi gb'ẹ'ni mi d'ókè odò
Ó bori idanwo, oyekooro láyé
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánitọ'mọ ńré lé rẹ' o
Ọlọkọ, jọwọ, bá mi ṣ'ẹni mi ní jẹ'jẹ
Ó ṣewọn to le ṣe o, o lana ayọ' kalẹ'
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánikẹ'mọ ńré lé o

Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere
Abánitọ'mọ ńré lé rẹ o
Olumuyiwa, Iyá Ẹgbẹ' Oní-ìhìnrere

Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA