Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Ojo Tuntun' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Musica Clasica para Estudiar

Varios-artistas

Hot Pop

Varios-artistas

Cheri Cheri Lady Radio

Varios-artistas

Gospel Hits Internacionais

Artist profile picture

Ojo Tuntun

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

A ìí f'ọmọ orè bọ'rè ni wón nwí (ni wón nwí)
Àwa ti ṣí'ṣọ lójú òrìsà (éèwò!)
Èèmò ṣakọ wọ' 'lú o (eeh-eeh), ìpónjú nló fà dání o

Kò s'óun ta lè gbé ṣe (ta lè gbé ṣe), kò mà s'óun ta lè dà
Bí ò bá s'áyọ' ní'lé o (k'ẹ máa gbọ' ará mi)
Òtúbántẹ' ni, òfo lásán
Bí ò sí idùnnú lódẹ'dẹ' o (haa...-haa...)
Òtúbántẹ' ni, òfo ló jẹ'

À nbẹ' yín ò ẹni ire
Jẹ' ká so'wọ' pò, ká fi'nú ko'nú
À nretí àtúntò, ìdẹ'ra
Ọwó wa la ó fi ṣé, la ó fi ṣé, la ó fi ṣé

Ẹ'té l'ọba àìṣóra, ìdààmú ní tèlé àìsètò
Èèmò g'ẹṣin wò 'lú o, ìfàsẹ'yìn àtìrandíran

Kò s'óun ta lè gbé ṣe (ta lè gbé ṣe), kò mà s'óun ta lè dà
Bí ò bá s'áyọ' ní'lé o (k'ẹ máa gbó ará mi)
Òtúbántẹ' ni, òfo lásán
Bí ò sí idùnnú lódèdè o (haa...-haa...)
Òtúbántẹ' ni, òfo ló jẹ'

À n'bẹ' yín ò ọlógbón ayé
Kẹ tọ' wa s'ónà àbáyọ s'íre
À n'retí àtúntò, ìdèra,
K'ójó tuntun tàn, yan, yan, yan (yan)

À nbè yín ò ẹni ire
Jẹ' ká so'wó pò, ká fi'nú ko'nú
À nretí àtúntò, ìdèra
Ọwó wa la ó fi ṣé

À nbè yín ò ọlógbón ayé
Kẹ tó wa s'ọ'nà àbáyọ s'íre
À n'retí àtúntò, ìdẹ'lèra,
K'ójó tuntun tàn, yan, yan, yan (yan)

Kò s'óun ta lè gbé ṣe (ta lè gbé ṣe), kò mà s'óun ta lè dà
Bí ò bá s'áyò ní'lé o
Òtúbántẹ' ni, òfo lásán
Bí ò ba sí ayo lódẹ'dẹ' o (haa...-haa...)
Òtúbántẹ' ni, òfo ló jẹ'

Bí ò bá s'áyò ní'lé o (k'ẹ máa gbó ará mi)
Òtúbántẹ' ni, òfo lásán
Bí ò sí idùnnú lódẹ'dẹ' o (haa...-haa...)
Òtúbántẹ' ni, òfo ló jẹ' (à nbẹ' yín ò ẹni ire)

Bí ò bá s'áyò ní'lé o (yee ema gbo)
Òtúbánté ni, òfo lásán (à nbè yín ò ọlógbón ayé)
Bí ò sí idùnnú lódèdè o (haa...-haa...)
Òtúbánté ni, òfo ló jẹ'

Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA