Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Kílẹ̀nwò' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

00s Dance

Varios-artistas

Top Hits Argentina

Varios-artistas

Girl Power

Varios-artistas

Musica para Jugar

Artist profile picture

Kílẹ̀nwò

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

Oponu ọmọ na fi ṣe'aṣọna
Dadandidin, afọfun ti o l'ero miran
A fi ka ti jẹun gbangba, ka ti kọ'le gagara
Ka ṣíṣẹ ara, ka ma wuga korofo

Baba, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Yeye, ki lẹ n wo? (Omi kọ ja afara)
Ẹgbọn, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Ọrẹ, ki lẹ n wo o? (Ori gongo orile)

Oponu ọmọ na fi ṣ'atọna
Akotileta ti o l'ero miran
Aa fi ka ti l'owo, ka ti k'ọrọ jọ
Ka f'eru gba 'bukun, Ìgbìmọ irọ

Aagbagba, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Ẹyin ọdọ, ki lẹ n wo o? (Ile ma n dahòrò)
Ah, ẹgbọn, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Ọrẹ, ki lẹ n wo o? (Ìlú ma n daṣálẹ)
Oponu ọmọ t'an fi ṣ'olori ni'lu olopurọ
Ko le ya ni lẹnu
B'oju o ba ti wọn o, oju n t'ẹnire
T'ori ọmọ to wọ lọja, ṣebí iyẹn lo ma n dun ni

Ahh, baba, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Yeye, ki lẹ n wo? (Omi kọ ja afara)
Ẹ'gbọn, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Ẹyin ọrẹ, ki lẹ n wo o? (Ori gongo orile)

Ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Ki lẹ n wo o?
Ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Ki lẹ n wo o?
Agbagba, ki lẹ n wo? (Ki lẹ n wo o?)
Ki lẹ n wo o?
Ẹyin ọdọ, ki lẹ n wo o? (Ki lẹ n wo o?)
Ki lẹ n wo o?
Ọrẹ, ki lẹ n wo o? (Ki lẹ n wo o?)
Ki lẹ n wo o?

Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA