Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Itana Odede' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Manana tranquila

Varios-artistas

Top Hits 2020

Varios-artistas

10s Pop Rock

Varios-artistas

New Dance

Artist profile picture

Itana Odede

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

Níbí wọn gbé ń ṣe'un tó yẹ kà ṣé láyé o
Níbí wọn gbé ń ṣe'un tó dára, ọrẹ (ọrẹ)
Níbí wọn gbé ń ṣeré aládùn, 'ládùn, 'ládùn, 'ládùn
Níbí wọn gbé ń ṣ'ájọyọ tẹrín-tọyaya

ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ṣé b'áwọn lo l'érè òní
ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo
ẸniỌbankẹ o (ìtànṣán oòrùn) ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn
ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o
Kà lọ, kà jọ débẹ o, woah-oh-oh

Ke s'ọmọdé pẹ'lú ọdọ, èwe àti májesìn
Ke s'ọkùnrin pel'ọkùnrin, àgbààgbà ìlù
Ke s'ẹní tí ńbẹ l'okò, tí ń ṣíṣẹ kò le dá
Ke s'ẹní tó re, tí ò l'àgbàrá mọ

Wípé, ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ṣé b'áwọn lo l'érè òní
ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo o
ẸniỌbankẹ o (ìtànṣán oòrùn) ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn
ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o
Kà lọ, kà jọ débẹ o, yea, oh

Má gbẹsẹ́ lọkánkán o, ní méjì-méjì
Áà tí b'orí ọfọ àti ìbànújẹ́, hmm
Máà mì bo wùn o oh
Ààní boo fẹ d'oókòtò
Ah, gbogbo wá là wá níbẹ, là wá níbẹ
Gbogbo wá là wá níbẹ, po!
(L'agbo onidẹra) gbogbo wá là to debẹ, ey
A pọ níbẹ', gbogbo wá là wá níbẹ, po!

Má gbẹsẹ́ lọkánkán o, ní méjì-méjì
Áà tí b'orí ọfọ àti ìbànújẹ́, ohh
Máà mì bo wùn o oh
Ààní boo fẹ d'oókòtò
Ehn? Gbogbo wá là wá níbẹ, ehh, à wá níbẹ
Gbogbo wá là wá níbẹ, po!
(L'agbo onidẹra) gbogbo wá là to debẹ, bẹẹni
A pọ níbẹ', gbogbo wá là wá níbẹ, po!

ẸniỌbankẹ (ẸniỌbankẹ) ehn, ṣé b'áwọ lo l'érè òní
ẸniỌbankẹ (ìtàna ọdẹdẹ) ṣé b'áwọn lo ń ṣe'jo o
ẸniỌbankẹ (ìtànṣán oòrùn) ehn, ṣéb'òun l'ọga òkùnkùn
ẸniỌbankẹ (atọnìsọna) ọrẹ, kà lọ, kà jọ débẹ o
Woah-oh-oh, kà lọ, kà jọ débẹ o, yea, oh-oh

ẸniỌbankẹ
Itàna ọdẹdẹ
Itànṣán oòrùn
Atọnìsọna

Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA