Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Ilé Ni O Wò' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Viajando Por Colombia

Varios-artistas

Tiktok Hits Latinos

Varios-artistas

90s Rap

Varios-artistas

Top Hits 1985

Artist profile picture

Ilé Ni O Wò

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

T'àwọn ile ni o wo, ni o wo, ni o wo, k'o to ṣe'un to fẹ ṣe, awe (to fẹ ṣe, awe)
Àwọn ẹlẹtan ọrẹ wọn a ni ko ma ṣe lọ, àwọn nw'ẹhin rẹ o
O ba dẹ wo ti baba, k'o wo ti yeye
Wo t'àwọn to fẹràn rẹ tọkantọkan
Mo ni, Ko ro t'ẹni rẹ, jọwọ, ko ro ti t'ọla, ro t'ọjọ atisun to n bọ wa o

T'ipilẹ ni o wo, ni o wo, ni o wo, k'o to ṣe'un to fẹ ṣe, awe (to fẹ ṣe, awe)
Àwọn ẹgbẹ mọdaru wọn a yin ẹ, wọn a ma ni, Aṣegbe ni t'oni o
O ba dẹ wo t'ọkàn rẹ, ah, wo t'ayọ rẹ
Wo tibalẹ ọkàn to wun ọ o
Mo ni, Ko ro t'ẹni rẹ, jọwọ, ko ro ti t'ọla, ro t'ọjọ atisun to n bọ wa o

Oju aye n wo ẹ, wọn n wo ẹ, jọwọ, rọra ṣe l'ode, awe (ṣe l'ode, awe)
Abatẹnijẹ ọrẹ, wọn a tan ẹ, wọn a ma pe, Ṣebí ìwọ lọga o
O ba dẹ f'ọgbọn ṣ'ẹgbọn o, f'ifura lo'gba
La'na idunnu f'àwọn to n bọ lọna
Mo ni, Ko ro t'ẹni rẹ, jọwọ, ko ro ti t'ọla, ro t'ọjọ atisun to n bọ wa o
Mo ni, Ko wo ti baba o, wo ti yeye
Wo t'àwọn to fẹràn rẹ tọkantọkan
Mo ni, Ko ro t'ẹni rẹ, jọwọ, ko ro ti t'ọla, ro t'ọjọ atisun to n bọ wa o

T'àwọn ile ni o wo, ni o wo