Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Ijo Oni' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Caliente

Varios-artistas

Latino Acustico

Varios-artistas

2000s Pop

Varios-artistas

Salsa Colombiana

Artist profile picture

Ijo Oni

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

Gbogbo ọmọdé èyin ni'jó kàn
Ẹ bọ' s'ágbo o, ijó òní yíò ládùn
Yíò lárinrin
Ẹy'in òdó ẹ'yin ni'jó kàn
Aani K'ẹ bọ' s'ágbo o, ká ṣ'eré, yíò ládùn Yíò lárinrin

Ijó ìdèra, ijó ìdùnnú, ijó ọpẹ', ijó ayò
Ijó àtúnjó, ijó tuntun, ijó àláfíà
Ijó àjọjó, ijó ẹgbẹ', fọwókanwọ' fẹsèlusè
Ijó àfapáfòbíẹyẹ, jùdí wùkè-wukẹ

Gbogbo ọmọge èyin ni'jó kàn
Ẹ bọ' s'ágbo o, ijó òní yíò ládùn, yíò lárinrin
Ẹy'in ìyá ẹ'yin ni'jó kàn
Moni k'ẹ bọ' s'ágbo o, ká ṣ'eré, yíò ládùn, yíò lárinrin

Gbogbo ọkùnrin ẹ'yin ni'jó kàn
Ẹ bó s'ágbo o, ijó òní yíò ládùn, yíò lárinrin
Gbogbo obìrin èyin ni'jó kàn
Aani bọ' s'ágbo o, ká ṣ'eré, yíò ládùn, yíò lárinrin

Ijó pèlé, ijó ìbùkún, ijó èré, ijó ògo
Kò s'ájèjì lójú agbo, ijó ìfẹ' ni o
Ijó ẹ'rín, ijó ìrètí, ijó ọlógbọ'n àt'ẹní nfẹ"re
Apá lọ'tun, ẹsẹ' losì, rè'dí rùbùkè-rubukẹ
Gbogbo ìlú ẹ'yin ni'jó kàn
Aani ke bó s'ágbo o, ijó òní yíò ládùn, yíò lárinrin

Gbogbo oníjó èyin ni'jó kàn
Aani K'ẹ bó s'ágbo o, ká ṣ'eré, yíò ládùn, yíò lárinrin

Ijó òní yíò ládùn, yíò lárinrin
Ijó òní yíò ládùn, yíò lárinrin
Ijó òní yíò ládùn, yíò lárinrin
Ijó òní yíò ládùn, yíò lárinrin

Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA