Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Guoguo' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Musica Variada De Todo Un Poco

Varios-artistas

Top Hits 2002

Varios-artistas

Hazbin Hotel

Varios-artistas

Musica Tranquila De Rio Para Relajar

Artist profile picture

Guoguo

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

Bí 'gbà bà mí dùn
Òun gbogbo a dá bí ere
Gbogbo àyé a má yìn o
Wọn a má pọn ẹ le l'ọtun, l'ósì o
Bí 'gbà bà yi pere
Gbogbo ilé a wá pa lọ-lọ
Wọn a má kí ní l'atọọkàn, woah
Ọwọ èpò, òun ní wón ń bá ní là o

Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná)

K'alẹ, kò lé dùn
Là ṣé ń jí l'ówúrò s'ìṣẹ
Ẹní àyé kàn kó lo jẹjẹ
Kà má fí t'ẹní p'ọlá o
Kò s'òun ta o rí-rí
A tí r'ọmọ aládé tó ń d'ẹrú
A dẹ tí r'ẹní tó ń ro pín, tó ń d'ọlọrọ
Kà má f'aigbọ'n jìn s'ọ̀gbun (ọ̀gbun)

Ṣébí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná)
Ilé wúràa má d áhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná)

Ṣé bí ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná)

Ohh, ilé wúrà a má dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná)

Ohh, ilé wúrà ń dáhòrò (ilé wúrà)
Owó ò hún kò má rà tí 'gbẹ̀yìn (owó ò hùn kò má rà tí 'gbẹ̀yìn)
Ẹ w'àwọn ọrẹ àná, ń pa guoguo
Wọn a ní, Mò rí o ná, mo ń bo (mo rí o ná)

Ilé wúrà
Owó ò hùn kò ra tí 'gbẹ̀yìn

Mo rí o ná
Ilé wúrà
Owó ò hùn kò rà tí 'gbẹ̀yìn

Mo rí o ná

Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA