Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'Eefo Egbe' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Esenciales Pop en Espanol

Varios-artistas

Throwback Pop

Varios-artistas

Top Hits 2020

Varios-artistas

Alt Running

Artist profile picture

Eefo Egbe

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá, wa ka lọ o
(Kà má'yọ wálé) jẹ ká lọ o (ma fòyà)
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o
(Kà má dùn wálé) 'ni ko jẹ ká lọ o (má bẹ̀rù)

Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto
Abaniṣe, k'ọlá ko lé dùn
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto
Abaniṣé, k'ọlá kò lé to

Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ o
(Kà má'yọ wálé) jẹ ká lọ o (ma fòyà)
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá o, wá ká lọ o
(Kà má dùn wálé) 'ni kò jẹ ká lọ o (má bẹ̀rù)

Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o
Ọkùnrin ìlù, oninure o
Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọ'la
Àwọn ọmọ ọ'la, ọmọ ọgbọn
Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o
Obìnrin ìlú, oninure o
Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọlá
Àwọn ọmọ iyì, ọmọ ọgbọn

Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ o
(Kà má'yọ wálé) jẹ ká lọ o (ma fòyà)
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá, wá ká lọ o
(Kà má dùn wálé) ani ko jẹ ká lọ o (má bẹ̀rù)

Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto
Abaniṣe, k'ọlá ko lé dùn
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', a mu're wọ'lú
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', onínúre o
Ìgbìmọ̀ Ẹgbẹ', atunluto
Abaniṣé, k'ọlá kò lé to
Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o
Ọkùnrin ìlù, oninure o
Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọ'la
Àwọn ọmọ ọ'la, ọmọ ọgbọn
Ke sọmọdé pel'àgbààgbà o
Obìnrin ìlú, oninure o
Ke s'àwọn ọdọ, ìrètí ọlá
Àwọn ọmọ iyì, ọmọ ọgbọn

Ẹgbẹ aládùn lo mí pé wá o, wa ka lọ o
(Kà má'yọ wálé) 'ni ko jẹ ká lọ o (ma fòyà)
Ẹgbẹ onire lo mí pe wá, wá ká lọ o
(Kà má dùn wálé) ọrẹ mí, jẹ ká lọ o (má bẹ̀rù)

Wa ka lọ
Jẹ ká lọ o

Ey-ey, oh-e, ey-ey (kà má'yọ wálé, ma fòyà)
Wa ka lọ
Ey-ey, oh-e, ey-ey (kà má dùn wálé, má bẹ̀rù)
Wà ká lọ
Ey-ey, oh-e, ey-ey (kà má'yọ wálé, ma fòyà)
Wà ká lọ

Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA