Inicio Top Música Bad Bunny Música Cristiana Taylor Swift Ed Sheeran Luis Fonsi Ozuna Daddy Yankee J Balvin Maluma DMCA

Letra de 'À Fi Nkọrin' de Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band - Escucha y canta en New Musicas

Varios-artistas

Dragon Ball Z

Varios-artistas

Musica para leer y estudiar

Varios-artistas

RAVE GYM

Varios-artistas

Explosion Mexico

Artist profile picture

À Fi Nkọrin

Beautiful Nubia And The Roots Renaissance Band

Canciones

Oju rẹ lo n pe mi o
Ẹrìn rẹ lo fa mi o, mo de
Mo mura ki n tẹle o de 'bugbe ayọ
Jọwọ, ro de mi o, ki n sọ fun ye mi
Jọwọ, mu mi de'bẹ o, mo ṣe tan

Yeye mi mo ma n r'ajo
Mo r'oun to wun mi, mo di mọ
Onitemi adunwo, onibugbe ayọ
Jọwọ, ro de mi o, ki n sọ fun ba' mi
Jọwọ, gbe mi de'bẹ o, mo ṣe tan

Oju o ii ri oun to dara to n dan ju wura lọ
Ẹnu o ii ba, oun to dara to dun j'oyin lọ
Ọrọ o le sọ bi mo ba ri o bo ṣe n ṣe l'ọkàn mi
A fi nkọrin ayọ, orin ayọ, idunnu
A fi nkọrin ayọ, orin ayọ, orin ifẹ
Oju rẹ lo wun mi o
Iwa rẹ lo fa mi o, mo de
Mo gbe'ra ki n tẹle o de 'bugbe ayo
Jọwọ, ro de mi o, ki nwi f'ẹni mi
Jọwọ, mu mi de'bẹ o, mo ṣe tan

Oju o ii ri oun to dara to n dan ju wura lọ
Ẹnu o ii ba, oun to dara to dun j'oyin lọ
Ọrọ o le sọ bi mo ba ri o bo ṣe n ṣe l'ọkàn mi
A fi nkọrin ayọ, orin ayọ, idunnu
A fi nkọrin ayọ, orin ayọ, orin ifẹ

Oju o ii ri oun to dara to n dan ju wura lọ
Ẹnu o ii ba, oun to dara to dun j'oyin lọ
Ọrọ o le sọ bi mo ba ri o bo ṣe n ṣe l'ọkàn mi
A fi nkọrin ayọ, orin ayọ, idunnu
A fi nkọrin ayọ, orin ayọ, orin ifẹ

Ẹnu o ii ba
Ọrọ o le sọ
Orin ayọ, idunnu
Orin ayọ, orin ifẹ